Orin Dafidi 96:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wí láàrin àwọn orílẹ̀-èdè pé, “OLUWA jọba!A ti fi ìdí ayé múlẹ̀, kò sì ní yẹ̀ lae;OLUWA yóo fi òtítọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan.”

Orin Dafidi 96

Orin Dafidi 96:2-13