Orin Dafidi 95:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á kọrin sí OLUWA;ẹ jẹ́ kí á hó ìhó ayọ̀ sí Olùdáàbòbò ati ìgbàlà wa!

Orin Dafidi 95

Orin Dafidi 95:1-10