Orin Dafidi 94:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, ìwọ Ọlọrun ẹ̀san,ìwọ Ọlọrun ẹ̀san, fi agbára rẹ hàn!

2. Dìde, ìwọ onídàájọ́ ayé;san ẹ̀san èrè iṣẹ́ àwọn agbéraga fún wọn!

3. OLUWA, yóo ti pẹ́ tó?Àní, yóo ti pẹ́ tó tí àwọn eniyan burúkú yóo máa ṣe jàgínní?

Orin Dafidi 94