Orin Dafidi 92:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ó dára kí eniyan máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, OLUWA;kí ó sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ, ìwọ Ọ̀gá Ògo;

2. ó dára kí eniyan máa kéde ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ní òwúrọ̀,kí ó máa kéde òtítọ́ rẹ ní alẹ́,

Orin Dafidi 92