Orin Dafidi 90:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Jẹ́ kí iṣẹ́ rẹ hàn sí àwọn iranṣẹ rẹ,kí agbára rẹ tí ó lógo sì hàn sí àwọn ọmọ wọn.

17. Jẹ́ kí ojurere OLUWA Ọlọrun wa wà lára wa,fi ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀,jẹ́ kí iṣẹ́ ọwọ́ wa fi ìdí múlẹ̀.

Orin Dafidi 90