Orin Dafidi 9:2 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo yọ̀, inú mi yóo sì máa dùn nítorí rẹ;n óo kọ orin ìyìn orúkọ rẹ, ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.

Orin Dafidi 9

Orin Dafidi 9:1-4