Orin Dafidi 89:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ta ni a lè fi wé ọ ní ọ̀run, OLUWA?Ta ni ó dàbí OLUWA láàrin àwọn ẹ̀dá ọ̀run?

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:1-13