Orin Dafidi 89:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ojú ọ̀run máa kọrin ìyìn iṣẹ́ ìyanu rẹ, OLÚWA;kí àwọn eniyan mímọ́ sì máa kọrin ìyìn òtítọ́ rẹ.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:1-11