Orin Dafidi 89:44-46 BIBELI MIMỌ (BM)

44. O ti gba ọ̀pá àṣẹ lọ́wọ́ rẹ̀;o sì ti wó ìtẹ́ rẹ̀ palẹ̀.

45. O ti gé ìgbà èwe rẹ̀ kúrú;o sì ti da ìtìjú bò ó.

46. Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA? Ṣé títí lae ni o óo máa fi ara pamọ́ fún mi?Yóo ti pẹ́ tó tí ibinu rẹ yóo máa jò bí iná?

Orin Dafidi 89