Orin Dafidi 88:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, Ọlọrun, Olùgbàlà mi, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́ ní ọ̀sán;mo ké níwájú rẹ ní òru.

Orin Dafidi 88

Orin Dafidi 88:1-3