Orin Dafidi 87:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn akọrin ati àwọn afunfèrè ati àwọn tí ń jó yóo máa sọ pé,“Ìwọ, Sioni, ni orísun gbogbo ire wa.”

Orin Dafidi 87

Orin Dafidi 87:1-7