Orin Dafidi 82:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Ẹ ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn mẹ̀kúnnù ati àwọn ọmọ aláìníbaba;ẹ sì máa ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn tí ojú ń pọ́n ati àwọn talaka.

4. Ẹ gba talaka ati aláìní sílẹ̀,ẹ gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú.”

5. Wọn kò ní ìmọ̀ tabi òye,wọ́n ń rìn kiri ninu òkùnkùn,títí gbogbo ìpìlẹ̀ ayé fi mì tìtì.

Orin Dafidi 82