Orin Dafidi 82:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn mẹ̀kúnnù ati àwọn ọmọ aláìníbaba;ẹ sì máa ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn tí ojú ń pọ́n ati àwọn talaka.

Orin Dafidi 82

Orin Dafidi 82:1-6