Orin Dafidi 81:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́, ẹ̀yin eniyan mi, nígbà tí mo báń kìlọ̀ fun yín,àní kí ẹ fetí sílẹ̀ sí mi, ẹ̀yin ọmọ Israẹli!

Orin Dafidi 81

Orin Dafidi 81:4-16