Orin Dafidi 81:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ìnira, o ké pè mí, mo sì gbà ọ́;mo dá ọ lóhùn ninu ìjì ààrá, níbi tí mo fara pamọ́ sí;mo sì dán ọ wò ninu omi odò Meriba.

Orin Dafidi 81

Orin Dafidi 81:3-10