Orin Dafidi 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ọwọ́ ati àwọn ọmọ-ọmú ń kọrin ògo rẹ,wọ́n ti fi ìdí agbára rẹ múlẹ̀,nítorí àwọn tí ó kórìíra rẹ,kí á lè pa àwọn ọ̀tá ati olùgbẹ̀san lẹ́nu mọ́.

Orin Dafidi 8

Orin Dafidi 8:1-6