Orin Dafidi 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, Oluwa wa,orúkọ rẹ níyìn pupọ ní gbogbo ayé!Ìwọ ni o gbé ògo rẹ kalẹ̀ lókè ọ̀run.

Orin Dafidi 8

Orin Dafidi 8:1-9