Orin Dafidi 79:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà, àwa eniyan rẹ,àní, àwa agbo aguntan pápá rẹ,yóo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ títí lae;a óo sì máa sọ̀rọ̀ ìyìn rẹ láti ìran dé ìran.

Orin Dafidi 79

Orin Dafidi 79:10-13