Orin Dafidi 78:8 BIBELI MIMỌ (BM)

kí wọn má dàbí àwọn baba ńlá wọn,ìran àwọn olóríkunkun ati ọlọ̀tẹ̀,àwọn tí ọkàn wọn kò dúró ṣinṣin,tí ẹ̀mí wọn kò sì dúró gbọningbọnin ti Olodumare.

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:1-13