Orin Dafidi 78:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí wọn lè gbẹ́kẹ̀lé Ọlọrun,kí wọn má gbàgbé iṣẹ́ rẹ̀,kí wọn sì máa pa òfin rẹ̀ mọ́,

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:1-12