Orin Dafidi 78:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbàkúùgbà tí ó bá ń pa wọ́n, wọn á wá a;wọn á ronupiwada, wọn á sì wá Ọlọrun tọkàntọkàn.

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:30-44