Orin Dafidi 78:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ó mú kí ọjọ́ ayé wọn pòórá bí afẹ́fẹ́;wọ́n sì lo ọjọ́ ayé wọn pẹlu ìjayà.

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:23-38