Orin Dafidi 77:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìkùukùu da omi òjò sílẹ̀,ojú ọ̀run sán ààrá;mànàmáná ń kọ yẹ̀rì káàkiri.

Orin Dafidi 77

Orin Dafidi 77:15-20