Orin Dafidi 77:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí omi òkun rí ọ, Ọlọrun,àní, nígbà tí omi òkun fi ojú kàn ọ́,ẹ̀rù bà á;ibú omi sì wárìrì.

Orin Dafidi 77

Orin Dafidi 77:6-20