Ranti ìjọ eniyan rẹ tí o ti rà ní ìgbà àtijọ́,àwọn ẹ̀yà tí o rà pada láti fi ṣe ogún tìrẹ;ranti òkè Sioni níbi tí o ti ń gbé rí.