Orin Dafidi 74:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, kí ló dé tí o fi ta wá nù títí ayé?Kí ló dé tí inú rẹ fi ń ru sí àwa aguntan pápá rẹ?

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:1-9