Orin Dafidi 74:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni o fọ́ àpáta tí omi tú jáde, tí odò sì ń ṣàn,ìwọ ni o sọ odò tí ń ṣàn di ilẹ̀ gbígbẹ.

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:12-22