Orin Dafidi 74:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni o fọ́ orí Lefiatani túútúú;o sì fi òkú rẹ̀ ṣe ìjẹ fún àwọn ẹranko inú aṣálẹ̀.

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:4-21