Orin Dafidi 73:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń fi ẹnu wọn sọ̀rọ̀ òdì sí Ọlọrun;wọn a sì máa sọ̀rọ̀ ìgbéraga káàkiri ayé.

Orin Dafidi 73

Orin Dafidi 73:1-11