Orin Dafidi 73:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sanra tóbẹ́ẹ̀ tí ojú wọn yíbò;èrò òmùgọ̀ sì kún ọkàn wọn ní àkúnwọ́sílẹ̀.

Orin Dafidi 73

Orin Dafidi 73:3-13