Orin Dafidi 73:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò ó! Ayé àwọn eniyan burúkú nìwọ̀nyí;ara dẹ̀ wọ́n nígbà gbogbo, ọrọ̀ wọn sì ń pọ̀ sí i.

Orin Dafidi 73

Orin Dafidi 73:4-17