Orin Dafidi 72:18-19 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Ẹni-ìyìn ni OLUWA Ọlọrun Israẹli,ẹni tí ó ń ṣe iṣẹ́ ìyanu tí ẹlòmíràn kò lè ṣe.

19. Ẹni ìyìn títí lae ni ẹni tí orúkọ rẹ̀ lókìkí,kí òkìkí rẹ̀ gba ayé kan!Amin! Amin.

Orin Dafidi 72