Orin Dafidi 71:20 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti jẹ́ kí n rí ọpọlọpọ ìpọ́njú ńlá,ṣugbọn óo tún mú ìgbé ayé mi pada bọ̀ sípò;óo tún ti gbé mi dìde láti inú isà òkú.

Orin Dafidi 71

Orin Dafidi 71:11-24