Orin Dafidi 71:1-3 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA, ìwọ ni mo sá di;má jẹ́ kí ojú ó tì mí laelae! Gbà mí, kí o sì yọ mí nítorí òdodo