Orin Dafidi 7:2-4 BIBELI MIMỌ (BM) Kí wọn má baà fà mí ya bíi kinniun,kí wọn máa wọ́ mi lọ láìsí ẹni tí ó lè gbà mí sílẹ̀.