Orin Dafidi 68:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọrin sí Ọlọrun, ẹ kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ̀,ẹ pòkìkí ẹni tí ń gun ìkùukùu lẹ́ṣin.OLUWA ni orúkọ rẹ̀;ẹ máa yọ̀ níwájú rẹ̀.

Orin Dafidi 68

Orin Dafidi 68:1-9