Orin Dafidi 68:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí inú àwọn olódodo máa dùn,kí wọn máa yọ̀ níwájú Ọlọrun;kí wọn máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀.

Orin Dafidi 68

Orin Dafidi 68:1-9