Orin Dafidi 66:18-20 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Bí mo bá gba ẹ̀ṣẹ̀ láyè ní ọkàn mi,OLUWA ìbá tí gbọ́ tèmi.

19. Ṣugbọn nítòótọ́, Ọlọrun ti gbọ́;ó sì ti dáhùn adura mi.

20. Ìyìn ni fún Ọlọrun,nítorí pé kò kọ adura mi;kò sì mú kí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ kúrò lórí mi.

Orin Dafidi 66