Orin Dafidi 67:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí Ọlọrun óo ṣàánú wa, kí ó bukun wa;kí ojú rẹ̀ tan ìmọ́lẹ̀ sí wa lára;

Orin Dafidi 67

Orin Dafidi 67:1-6