Orin Dafidi 66:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wá gbọ́, gbogbo ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Ọlọrun,n óo sì ròyìn ohun tí ó ṣe fún mi.

Orin Dafidi 66

Orin Dafidi 66:12-20