Orin Dafidi 66:15 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi ẹran àbọ́pa rú ẹbọ sísun sí ọ,èéfín ẹbọ àgbò yóo rú sókè ọ̀run,n óo fi akọ mààlúù ati òbúkọ rúbọ.

Orin Dafidi 66

Orin Dafidi 66:12-20