Orin Dafidi 65:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ tí o fi agbára fi ìdí àwọn òkè ńlá múlẹ̀;tí o sì fi agbára di ara rẹ ní àmùrè.

Orin Dafidi 65

Orin Dafidi 65:2-13