Orin Dafidi 65:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣẹ́ òdodo tí ó bani lẹ́rù ni o fi dá wa lóhùn,Ọlọrun olùgbàlà wa.Ìwọ ni gbogbo àwọn tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé gbẹ́kẹ̀lé,ati àwọn tí wọn wà lórí omi òkun ní ọ̀nà jíjìn réré.

Orin Dafidi 65

Orin Dafidi 65:1-9