Orin Dafidi 62:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Afẹ́fẹ́ lásán ni àwọn mẹ̀kúnnù;ìtànjẹ patapata sì ni àwọn ọlọ́lá;bí a bá gbé wọn lé ìwọ̀n, wọn kò lè tẹ̀wọ̀n;àpapọ̀ wọn fúyẹ́ ju afẹ́fẹ́ lọ.

Orin Dafidi 62

Orin Dafidi 62:2-12