Orin Dafidi 62:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbẹ́kẹ̀lé e nígbà gbogbo, ẹ̀yin eniyan;ẹ tú ẹ̀dùn ọkàn yín palẹ̀ níwájú rẹ̀;OLUWA ni ààbò wa.

Orin Dafidi 62

Orin Dafidi 62:4-12