Orin Dafidi 61:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ọ̀nà jíjìn réré ni mo ti ké pè ọ́,nígbà tí àárẹ̀ mú mi.Tọ́ mi lọ sí ibi àpáta tí ó ga jù mí lọ,

Orin Dafidi 61

Orin Dafidi 61:1-8