Orin Dafidi 59:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, agbára mi, n óo kọ orin ìyìn fún ọ,nítorí ìwọ, Ọlọrun, ni odi mi,Ọlọrun tí ó ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn mí.

Orin Dafidi 59

Orin Dafidi 59:14-17