Orin Dafidi 59:13 BIBELI MIMỌ (BM)

fi ibinu pa wọ́n run.Pa wọ́n run kí wọn má sí mọ́,kí àwọn eniyan lè mọ̀ pé Ọlọrun jọba lórí Jakọbu,ati títí dé òpin ayé.

Orin Dafidi 59

Orin Dafidi 59:7-17