Orin Dafidi 59:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n fi ẹnu wọn dá,àní, nítorí ọ̀rọ̀ tí wọ́n fi ẹnu wọn sọ,jẹ́ kí ìgbéraga wọn kó bá wọn.Nítorí èpè tí wọ́n ṣẹ́ ati irọ́ tí wọ́n pa,

Orin Dafidi 59

Orin Dafidi 59:8-17