Orin Dafidi 57:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ṣàánú mi, Ọlọrun, ṣàánú mi,nítorí ìwọ ni ààbò mi;abẹ́ òjìji apá rẹ ni n óo fi ṣe ààbò mi,títí gbogbo àjálù wọnyi yóo fi kọjá.

2. Mo ké pe Ọlọrun Ọ̀gá Ògo,Ọlọrun tí ó mú èrò rẹ̀ ṣẹ fún mi.

Orin Dafidi 57